Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 25:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Abigaili bá yára mú igba (200) burẹdi ati ìgò ọtí waini meji ati aguntan marun-un tí wọ́n ti sè ati òṣùnwọ̀n ọkà yíyan marun-un ati ọgọrun-un ìdì àjàrà gbígbẹ ati igba (200) àkàrà tí wọ́n fi èso ọ̀pọ̀tọ́ dín, ó sì dì wọ́n ru kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 25

Wo Samuẹli Kinni 25:18 ni o tọ