Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 25:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi sì pàṣẹ fún àwọn eniyan rẹ̀ pé, “Ẹ sán idà yín mọ́ ìdí.” Gbogbo wọn sì ṣe bí ó ti wí; òun pàápàá sì sán idà tirẹ̀ náà mọ́ ìdí. Irinwo ninu àwọn ọdọmọkunrin rẹ̀ bá a lọ; igba (200) sì dúró ti ẹrù wọn.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 25

Wo Samuẹli Kinni 25:13 ni o tọ