Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 24:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn tí wọ́n wà lọ́dọ̀ Dafidi sọ fún un pé, “Òní gan-an ni ọjọ́ tí OLUWA ti sọ fún ọ nípa rẹ̀, pé òun yóo fi ọ̀tá rẹ lé ọ lọ́wọ́, kí o lè ṣe é bí ó ti wù ọ́.” Dafidi bá yọ́ kẹ́lẹ́kẹ́lẹ́ lọ sí ibi tí Saulu wà, ó sì gé etí aṣọ rẹ̀.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 24

Wo Samuẹli Kinni 24:4 ni o tọ