Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 23:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Saulu ati àwọn eniyan rẹ̀ wà ní apá kan òkè náà, Dafidi ati àwọn eniyan rẹ̀ sì wà ní apá keji. Dafidi ati àwọn eniyan rẹ̀ ń múra láti sá fún Saulu ati àwọn eniyan rẹ̀ nítorí pé wọ́n ń rọ̀gbà yí wọn ká láti mú wọn.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 23

Wo Samuẹli Kinni 23:26 ni o tọ