Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 23:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ mọ gbogbo ibi tíí máa ń sá pamọ́ sí dájúdájú, kí ẹ sì wá ròyìn fún mi. N óo ba yín lọ; bí ó bá wà níbẹ̀, n óo wá a kàn, bí ó bá tilẹ̀ wà láàrin ẹgbẹẹgbẹrun eniyan ilẹ̀ Juda.”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 23

Wo Samuẹli Kinni 23:23 ni o tọ