Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 23:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi bá ń lọ gbé orí òkè kan tí ó ṣe é farapamọ́ sí ní aṣálẹ̀ Sifi. Saulu ń wá a lojoojumọ láti pa á, ṣugbọn Ọlọrun kò fi Dafidi lé e lọ́wọ́.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 23

Wo Samuẹli Kinni 23:14 ni o tọ