Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 23:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi tún bèèrè pé, “Ǹjẹ́ àwọn alàgbà Keila yóo fà mí lé e lọ́wọ́?”OLUWA dáhùn pé, “Bẹ́ẹ̀ ni, wọn yóo fà ọ́ lé e lọ́wọ́.”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 23

Wo Samuẹli Kinni 23:12 ni o tọ