Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 22:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Wolii Gadi sọ fún Dafidi pé, “Má dúró níbi ìpamọ́ yìí mọ́, múra, kí o lọ sí ilẹ̀ Juda.” Dafidi bá lọ sí igbó Hereti.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 22

Wo Samuẹli Kinni 22:5 ni o tọ