Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 22:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi dá a lóhùn pé, “Nígbà tí mo ti rí Doegi níbẹ̀ ní ọjọ́ náà ni mo ti fura pé yóo sọ fún Saulu. Nítorí náà, ẹ̀bi ikú àwọn eniyan rẹ wà lọ́rùn mi.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 22

Wo Samuẹli Kinni 22:22 ni o tọ