Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 22:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo àwọn tí wọ́n wà ninu ìpọ́njú, ati àwọn tí wọ́n jẹ gbèsè ati àwọn tí wọ́n wà ninu ìbànújẹ́ sá wá sọ́dọ̀ rẹ̀. Gbogbo wọn jẹ́ irinwo (400) ọkunrin, ó sì jẹ́ olórí wọn.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 22

Wo Samuẹli Kinni 22:2 ni o tọ