Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 22:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọba bá pàṣẹ fún àwọn ọmọ ogun tí wọ́n wà lọ́dọ̀ rẹ̀ pé, “Ẹ pa àwọn alufaa OLUWA nítorí pé wọ́n wà lẹ́yìn Dafidi, wọ́n mọ̀ pé ó ń sá lọ, wọn kò sì sọ fún mi.” Ṣugbọn àwọn ọmọ ogun náà kọ̀ láti pa àwọn alufaa OLUWA.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 22

Wo Samuẹli Kinni 22:17 ni o tọ