Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 22:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Ǹjẹ́ èyí ha ni ìgbà àkọ́kọ́ tí mo bá a ṣe ìwádìí lọ́dọ̀ Ọlọ́run? Rárá o! Nítorí náà kí ọba má ṣe ka ẹ̀sùn kankan sí èmi ati ìdílé baba mi lẹ́sẹ̀, nítorí pé, èmi iranṣẹ rẹ, kò mọ nǹkankan nípa ọ̀tẹ̀ tí Dafidi dì sí ọ.”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 22

Wo Samuẹli Kinni 22:15 ni o tọ