Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 22:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Saulu bi í pé, “Kí ló dé tí ìwọ ati ọmọ Jese fi gbìmọ̀ burúkú sí mi? Tí o fún un ní oúnjẹ ati idà, tí o sì tún bá a ṣe ìwádìí lọ́dọ̀ Ọlọrun. Dafidi ti lòdì sí mi báyìí, ó sì ti ba dè mí, láti pa mí.”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 22

Wo Samuẹli Kinni 22:13 ni o tọ