Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 21:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Alufaa kó àwọn burẹdi mímọ́ náà fún Dafidi, nítorí pé kò sí òmíràn níbẹ̀, àfi burẹdi ìfihàn tí wọ́n kó kúrò níwájú OLUWA láti fi òmíràn rọ́pò rẹ̀.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 21

Wo Samuẹli Kinni 21:6 ni o tọ