Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 21:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn iranṣẹ Akiṣi sì sọ fún un pé, “Ǹjẹ́ Dafidi, ọba ilẹ̀ rẹ̀ kọ́ nìyí, tí àwọn obinrin ń kọrin nípa rẹ̀ pé:‘Saulu pa ẹgbẹrun tirẹ̀,Dafidi sì pa ẹgbẹẹgbaarun tirẹ̀?’ ”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 21

Wo Samuẹli Kinni 21:11 ni o tọ