Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 20:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà ṣe èmi iranṣẹ rẹ ní oore kan, nítorí o ti mú mi dá majẹmu mímọ́ pẹlu rẹ. Ṣugbọn bí o bá rí ohun tí ó burú ninu ìwà mi, ìwọ gan-an ni kí o pa mí; má wulẹ̀ fà mí lé baba rẹ lọ́wọ́ láti pa.”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 20

Wo Samuẹli Kinni 20:8 ni o tọ