Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 20:34 BIBELI MIMỌ (BM)

Jonatani sì fi ibinu dìde kúrò ní ìdí tabili oúnjẹ, kò sì jẹun ní ọjọ́ náà, tíí ṣe ọjọ́ keji oṣù. Inú rẹ̀ bàjẹ́ gidigidi fún Dafidi, nítorí pé baba rẹ̀ dójú tì í.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 20

Wo Samuẹli Kinni 20:34 ni o tọ