Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 20:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi dáhùn pé, “Baba rẹ mọ̀ wí pé bí òun bá sọ fún ọ, inú rẹ kò ní dùn, nítorí pé o fẹ́ràn mi. Nítòótọ́ bí OLUWA tí ń bẹ láàyè, tí ẹ̀mí rẹ náà sì ń bẹ láàyè, ìṣísẹ̀ kan ló wà láàrin èmi ati ikú.”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 20

Wo Samuẹli Kinni 20:3 ni o tọ