Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 20:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Sibẹ Saulu kò sọ nǹkankan nítorí pé ó rò pé bóyá nǹkankan ti ṣẹlẹ̀ sí Dafidi, tí ó sì sọ ọ́ di aláìmọ́ ni.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 20

Wo Samuẹli Kinni 20:26 ni o tọ