Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 2:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹnìkan ninu ìdílé rẹ tí n kò ní mú kúrò ní ibi pẹpẹ mi, yóo sọkún títí tí ojú rẹ̀ yóo fi di bàìbàì, ọkàn rẹ̀ yóo sì kún fún ìbànújẹ́. Gbogbo ọmọ inú ilé rẹ ni wọn yóo fi idà pa ní ọjọ́ àìpé.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 2

Wo Samuẹli Kinni 2:33 ni o tọ