Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 2:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Ninu gbogbo ẹ̀yà tí ó wà ní Israẹli, ìdílé baba rẹ nìkan ni mo yàn láti jẹ́ alufaa mi, pé kí ẹ máa ṣe iṣẹ́ alufaa níbi pẹpẹ, kí ẹ máa sun turari kí ẹ máa wọ ẹ̀wù efodu, kí ẹ sì máa wádìí nǹkan lọ́wọ́ mi. Mo fún wọn ní gbogbo ẹbọ sísun tí àwọn ọmọ Israẹli bá rú sí mi.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 2

Wo Samuẹli Kinni 2:28 ni o tọ