Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 2:21 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA bukun Hana: ọmọkunrin mẹta, ati ọmọbinrin meji ni ó tún bí lẹ́yìn Samuẹli. Samuẹli sì ń dàgbà níbi tí ó ti ń ṣe iṣẹ́ iranṣẹ sin OLUWA.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 2

Wo Samuẹli Kinni 2:21 ni o tọ