Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 2:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Hana bá gbadura báyìí pé:“Ọkàn mi kún fún ayọ̀ ninu OLUWA,Ó sọ mí di alágbára;mò ń fi àwọn ọ̀tá mi rẹ́rìn-ín,nítorí mò ń yọ̀ pé OLUWA gbà mí là.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 2

Wo Samuẹli Kinni 2:1 ni o tọ