Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 19:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bọ́ aṣọ rẹ̀, ó sì sọ àsọtẹ́lẹ̀ níwájú Samuẹli. Ó sùn ní ìhòòhò ní ọ̀sán ati òru ọjọ́ náà. Àwọn eniyan sì bẹ̀rẹ̀ sí sọ wí pé, “Àbí Saulu náà ti di wolii?”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 19

Wo Samuẹli Kinni 19:24 ni o tọ