Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 19:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Òun pàápàá dìde ó lọ sí Rama. Nígbà tí ó dé etí kànga jíjìn tí ó wà ní Seku, ó bèèrè ibi tí Samuẹli ati Dafidi wà. Wọ́n sì sọ fún un wí pé, wọ́n wà ní Naioti ti Rama.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 19

Wo Samuẹli Kinni 19:22 ni o tọ