Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 19:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi sá àsálà, ó sá lọ sí ọ̀dọ̀ Samuẹli ní Rama, ó sọ gbogbo ohun tí Saulu ti ṣe sí i fún un. Òun pẹlu Samuẹli sì lọ ń gbé Naioti.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 19

Wo Samuẹli Kinni 19:18 ni o tọ