Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 19:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Saulu sọ fún ọmọ rẹ̀ Jonatani ati gbogbo àwọn iranṣẹ rẹ̀ pé kí wọ́n pa Dafidi. Ṣugbọn Jonatani fẹ́ràn Dafidi lọpọlọpọ.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 19

Wo Samuẹli Kinni 19:1 ni o tọ