Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 18:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Ninu gbogbo ogun tí wọ́n bá àwọn ara Filistia jà, Dafidi ní ìṣẹ́gun ju gbogbo àwọn olórí ogun Saulu yòókù lọ. Ó sì jẹ́ olókìkí láàrin wọn.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 18

Wo Samuẹli Kinni 18:30 ni o tọ