Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 18:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Saulu sì rán wọn pé kí wọ́n sọ fún Dafidi pé, “Ọba kò bèèrè ẹ̀bùn igbeyawo kankan lọ́wọ́ rẹ ju ọgọrun-un awọ orí adọ̀dọ́ àwọn ará Filistia, gẹ́gẹ́ bí ẹ̀san lára àwọn ọ̀tá ọba.” Saulu rò pé àwọn ará Filistia yóo tipa bẹ́ẹ̀ pa Dafidi.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 18

Wo Samuẹli Kinni 18:25 ni o tọ