Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 18:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ keji, ẹ̀mí burúkú láti ọ̀dọ̀ Ọlọrun bà lé Saulu, ó sì ń sọ kántankàntan láàrin ilé rẹ̀. Dafidi bẹ̀rẹ̀ sí ta hapu fún un gẹ́gẹ́ bí ó ti ń ṣe tẹ́lẹ̀. Ọ̀kọ̀ kan wà lọ́wọ́ Saulu.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 18

Wo Samuẹli Kinni 18:10 ni o tọ