Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 17:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Goliati dúró, ó sì kígbe pe àwọn ọmọ Israẹli, ó ní, “Kí ló dé tí ẹ fi kó ara yín jọ láti jagun? Ṣebí Filistini kan ni èmi, ẹ̀yin náà sì jẹ́ ẹrú Saulu? Ẹ̀yin ẹ yan ọkunrin kan láàrin yín tí yóo sọ̀kalẹ̀ wá bá mi jà.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 17

Wo Samuẹli Kinni 17:8 ni o tọ