Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 17:51 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi sáré sí Goliati, ó yọ idà Goliati kúrò ninu àkọ̀, ó sì fi gé orí rẹ̀. Nígbà tí àwọn ọmọ ogun Filistini rí i pé akikanju àwọn ti kú, wọ́n bá bẹ̀rẹ̀ sí sá lọ.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 17

Wo Samuẹli Kinni 17:51 ni o tọ