Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 17:49 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi mú òkúta kan jáde láti inú àpò rẹ̀, ó fi kànnàkànnà rẹ̀ ta òkúta náà, òkúta náà wọ agbárí Goliati lọ, ó sì ṣubú lulẹ̀.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 17

Wo Samuẹli Kinni 17:49 ni o tọ