Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 17:40 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó mú ọ̀pá darandaran rẹ̀, ó ṣa òkúta marun-un tí ń dán ninu odò, ó kó wọn sinu àpò rẹ̀, ó mú kànnàkànnà rẹ̀ lọ́wọ́, ó sì lọ bá Filistini náà.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 17

Wo Samuẹli Kinni 17:40 ni o tọ