Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 17:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ kan, Jese sọ fún Dafidi pé, “Jọ̀wọ́, mú ìwọ̀n efa àgbàdo yíyan kan, ati burẹdi mẹ́wàá yìí lọ fún àwọn ẹ̀gbọ́n rẹ ní ibùdó ogun.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 17

Wo Samuẹli Kinni 17:17 ni o tọ