Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 16:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí wọ́n dé, ó wo Eliabu, ó sì wí ninu ara rẹ̀ pé, “Dájúdájú ẹni tí OLUWA yàn nìyí.”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 16

Wo Samuẹli Kinni 16:6 ni o tọ