Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 16:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbàkúùgbà tí ẹ̀mí burúkú bá ti ọ̀dọ̀ OLUWA wá sórí Saulu, Dafidi a máa ta hapu fún un, ara Saulu á balẹ̀, ẹ̀mí burúkú náà a sì fi í sílẹ̀.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 16

Wo Samuẹli Kinni 16:23 ni o tọ