Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 16:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Samuẹli dáhùn pé, “Báwo ni n óo ṣe lọ? Bí Saulu bá gbọ́, pípa ni yóo pa mí.”OLUWA dá a lóhùn pé, “Mú ọ̀dọ́ mààlúù kan lọ́wọ́, kí o wí pé o wá rúbọ sí OLUWA ni.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 16

Wo Samuẹli Kinni 16:2 ni o tọ