Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 16:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọ̀kan ninu àwọn ọdọmọkunrin náà dáhùn pé, “Wò ó! Mo ti rí ọmọ Jese ará Bẹtilẹhẹmu tí ó mọ hapu ta dáradára. Ó jẹ́ alágbára ati akọni lójú ogun, ó ní ọ̀rọ̀ rere lẹ́nu, ó lẹ́wà, OLUWA sì wà pẹlu rẹ̀.”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 16

Wo Samuẹli Kinni 16:18 ni o tọ