Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 16:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà ni Samuẹli mú ìwo tí òróró wà ninu rẹ̀, ó ta òróró náà sí i lórí láàrin àwọn arakunrin rẹ̀, Ẹ̀mí OLUWA sì bà lé Dafidi láti ọjọ́ náà lọ. Samuẹli bá gbéra, ó pada sí Rama.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 16

Wo Samuẹli Kinni 16:13 ni o tọ