Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 15:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Saulu ati àwọn eniyan rẹ̀ dá Agagi sí, wọn kò sì pa àwọn tí wọ́n dára jùlọ ninu àwọn aguntan, mààlúù, ati ọ̀dọ́ mààlúù ati ọ̀dọ́ aguntan wọn, ati àwọn nǹkan mìíràn tí ó dára. Wọn kò pa wọ́n run, ṣugbọn wọ́n pa àwọn ohun tí kò níláárí run.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 15

Wo Samuẹli Kinni 15:9 ni o tọ