Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 15:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Saulu dá a lóhùn pé, “Mo mọ̀ pé mo ti ṣẹ̀, ṣugbọn bu ọlá fún mi níwájú àwọn àgbààgbà, àwọn eniyan mi ati gbogbo Israẹli. Bá mi pada lọ, kí n lọ sin OLUWA Ọlọrun rẹ.”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 15

Wo Samuẹli Kinni 15:30 ni o tọ