Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 15:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Samuẹli bá bi í pé, “Èwo ló dùn mọ́ OLUWA jù, ìgbọràn ni, tabi ọrẹ ati ẹbọ sísun?” Ó ní, “Gbọ́! Ìgbọràn dára ju ẹbọ lọ, ìfetísílẹ̀ sì dára ju ọ̀rá àgbò lọ.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 15

Wo Samuẹli Kinni 15:22 ni o tọ