Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 15:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó sì rán ọ jáde pẹlu àṣẹ pé kí o pa gbogbo àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀, ará Amaleki run. Ó ní kí o gbógun tì wọ́n títí o óo fi pa wọ́n run patapata.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 15

Wo Samuẹli Kinni 15:18 ni o tọ