Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 15:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Saulu dá a lóhùn pé, “Àwọn eniyan mi ni wọ́n kó wọn lọ́dọ̀ àwọn ará Amaleki. Wọ́n ṣa àwọn aguntan ati àwọn mààlúù tí wọ́n dára jùlọ pamọ́ láti fi rúbọ sí OLUWA Ọlọrun rẹ. A sì ti pa gbogbo àwọn yòókù run patapata.”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 15

Wo Samuẹli Kinni 15:15 ni o tọ