Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 14:52 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo ọjọ́ ayé Saulu ni ó fi bá àwọn ará Filistia jagun kíkankíkan. Nígbà gbogbo tí Saulu bá sì ti rí ọkunrin tí ó jẹ́ alágbára tabi akikanju, a máa fi kún àwọn ọmọ ogun rẹ̀.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 14

Wo Samuẹli Kinni 14:52 ni o tọ