Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 14:47 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn tí Saulu ti di ọba Israẹli tán, ó bẹ̀rẹ̀ sí bá àwọn ọ̀tá tí wọ́n yí i ká jagun; àwọn bíi: Moabu, Amoni, ati Edomu, ọba ilẹ̀ Soba, ati ti ilẹ̀ Filistini. Ní gbogbo ibi tí ó ti jagun ni ó ti pa wọ́n ní ìpakúpa.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 14

Wo Samuẹli Kinni 14:47 ni o tọ