Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 14:43 BIBELI MIMỌ (BM)

Saulu bèèrè lọ́wọ́ Jonatani pé kí ó sọ ohun tí ó ṣe fún òun.Jonatani dá a lóhùn pé, “Mo ti ọ̀pá tí mo mú lọ́wọ́ bọ inú oyin, mo sì lá a. Èmi nìyí, mo ṣetán láti kú.”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 14

Wo Samuẹli Kinni 14:43 ni o tọ