Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 14:41 BIBELI MIMỌ (BM)

Saulu bá ní, “OLUWA Ọlọrun Israẹli, kí ló dé tí o kò fi dá iranṣẹ rẹ lóhùn lónìí? OLUWA Ọlọrun Israẹli, bí ó bá jẹ́ pé èmi tabi Jonatani ni a jẹ̀bi, fi Urimu dáhùn. Ṣugbọn bí ó bá jẹ́ pé àwọn eniyan rẹ ni wọ́n ṣẹ̀, fi Tumimu dáhùn.” Urimu bá mú Jonatani ati Saulu,

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 14

Wo Samuẹli Kinni 14:41 ni o tọ