Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 14:37 BIBELI MIMỌ (BM)

Saulu bá bèèrè lọ́wọ́ Ọlọrun pé, “Ṣé kí n lọ kọlu àwọn ará Filistia? Ṣé o óo fún Israẹli ní ìṣẹ́gun?” Ṣugbọn Ọlọrun kò dá a lóhùn ní ọjọ́ náà.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 14

Wo Samuẹli Kinni 14:37 ni o tọ